
“Modupe Temi” is a powerful song, a manifestation of divine inspiration, crafted by the talented artist Eniolamisings. This song has the power to resonate deeply within you and elevate your soul. Download now
Lyrics
Oluwa ah ah
Oluwa ah ah
MO dupe temi o
To o ba seleyi talolemu o si
Opo Egbe mi lo wo so jade Nile to ku si igboro
O je ki aye mu Awon eniyan losi Ibi iboji mi/2x
Ni tori jijade ati wiwole mi Owo re lo wa/2x
Oluwa ah ah
Oluwa ah ah
Mo dupe temi
To ba seyi koseni tolemu o si
Mo dupe temi o
To ba damisi ta lofe mu o
Opo Egbe mi lo woso Nile to ku si igboro
Opo Egbe mi lo woso Nile Aso lo fi dawon mo ni ta
O je ki aye mu Awon eniyan lo si Ibi iboji mi
O je o fi irun mi dami mo ni mortuary
O je o fi Aso dami mo
Nitori jijade ati wiwole mi Owo re lowa o
Nitori jije mimu mi Jesu Owo re lo wa o
Bi mo se nlo ti mo n bo nigbagbogbo Olorun Owo re lo wa
Oluwa ah ah
Oluwa ah ah
Oluwa ah ah